Yoruba Hymn APA 72- Onidajo mbo wa
APA 72
1. Onidajo mbo wa,
Awon oku jinde,
Enikan ko le yo kuro
’Nu mole oju Re.
2. Enu ododo Re
Yio da ebi fun
Awon t’o so anu Re nu;
Ti nwon se buburu.
3. “Lo kuro lodo mi
S’ ina ’ti ko lopin
Ti a ti pese fun Esu
T’o ti nsote si mi.”
4. Iwo ti duro to!
Ojo na o mbo wa,
T’aiye at’ orun o fo lo
kuro ni wiwa Re. Amin.
Yoruba Hymn APA 72- Onidajo mbo wa
This is Yoruba Anglican hymns, APA 72 - Onidajo mbo wa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.