Yoruba Hymn APA 67 - Jesu kigbe pe, “Emi de

Yoruba Hymn APA 67 - Jesu kigbe pe, “Emi de

 Yoruba Hymn APA 67 - Jesu kigbe pe, “Emi de

APA 67

 1. Jesu kigbe pe, “Emi de,

 T’ emi ti ife nla”

 Okan mi dahun pe, “Ma bo,”

 K’ o mu igbala wa.


2. Wa, gba oran Baba Re ro;

 Si mu ogo Re ran;

 Wa, ji oku iranse Re,

 K’ o si so won d’ otun.


3. Ma bo wa ’larin ogun Re

 Lati gb’oruko won;

 K’ o si m’ ajo kikun pada

 Lati y’ ite Re ka.

 

4. Olurapada, wa Kankan,

 Mu ojo nla ni wa.

 Wa, k’ okan wa ma ba daku,

 Nitori pipe Re. Amin.

Yoruba Hymn APA 67 - Jesu kigbe pe, “Emi de

This is Yoruba Anglican hymns, APA 67 - Jesu kigbe pe, “Emi de. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post