Yoruba Hymn APA 60 - Mole t’o da gbogbo nkan

Yoruba Hymn APA 60 - Mole t’o da gbogbo nkan

Yoruba Hymn  APA  60 - Mole t’o da gbogbo nkan

APA 60

1. ’Mole t’o da gbogbo nkan,

 N I pipe, lati ’n’ okun,

 K’a pin n’ n’ewa on’ bukun Re.

 Wa sodo wa.


2. ’Mole t’ o joba aiye,

 ’Mole t’ o fun wa n’ iye;

 A ! Imole t’o ns’ atunda,

 Wa sodo wa.


3. Imole t’o wa s’aiye,

 ’Mole t’ o nw’ oju eda,

 T’o ku l’okunkun b’enia,

 Wa sodo wa.


4. ’Mole t’o de ’po ’rele,

 T’ o tun lo soke giga,

 T’o si wa pelu wa sibe,

 Wa sodo wa.


5. ’Mole t’o nfun wa l’oye,

 ’Mole t’o nse wa lewa,

 Imole ti nf’ ayo simi,

 Wa sodo wa.


6. Mase je k’a pe a ri,

 ’Gbat’a diju wa si O,

 Enit’o nfi suru kankun

 Wole, ma bo.


7. Tire ni gbogbo ’re wa;

 Tiwa ni gbogbo ibi;

 Jo le won kuro lodo Re,

 Wa sodo wa.


8. Mu ’se okunkun kuro;

 Di wa ni hamora Re,

 K’ a rin n’nu ’mole k’a ma so

 Atunwa Re.


9. Awa se O pupo ju’

 Sibe Tire l’awa se;

 Je k’aiye wa j’orin si O’

 Wa sodo wa.


10. Wa ninu Olanla Re,

 Ni titobi ’rele Re;

 Wa, gbogbo aiye nkepe O

 Wa sodo wa. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 60 - Mole t’o da gbogbo nkan. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post