Yoruba Hymn APA 59 - Wa iwo Jesu t’ a nreti
APA 59
1. Wa iwo Jesu t’ a nreti
T’ a bi lati da ni n’ de,
Gba wa low’ eru at’ ese
Je k’ a ri isimi re:
2. Iwo ni itunu Israel,
Ireti Onigbagbo;
Ife gbogb’ orile-ede
Ayo okan ti nwona.
3. ’Wo t’ a bi lati gba wa la,
Omo ti a bi l’ Oba;
Ti a bi lati job alai,
Je ki ijoba Re de:
4. Fi Emi Mimo Re nikan,
Se akoso aiya wa;
Nipa itoye kikun Re
Gbe wa s’ ori ite Re. Amin.
This is Yoruba Anglican hymns, APA 59 - Wa iwo Jesu t’ a nreti. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.