Yoruba Hymn APA 57 - Wo oju sanma ohun ni

Yoruba Hymn APA 57 - Wo oju sanma ohun ni

  Yoruba Hymn APA 57 - Wo oju sanma ohun ni

APA 57

1. Wo oju sanma ohun ni,

 Wo lila orun oro;

 Ji l’ oju orun, okan mi,

 Dide k’ o si ma sora;

 Olugbala, Olugbala,

 Tun npada bow a saiye.


2. O pe ti mo ti nreti Re,

 L’ are l’ okan mi nduro,

 Aiye ko ni ayo fun mi,

 Nibiti ko tan mole.

 Olugbala, Olugbala,

 ’Gbawo ni ’wo o pada?


3. Igbala mi sunm’ etile,

 Oru fere koja na,

 Je ki nwa n’ ipo irele,

 Ki ns’ afojusona Re.

 Olugbala, Olugbala,

 Titi ngo fi r’ oju Re


4. Je ki fitila mi ma jo,

 Kim ma sako kiri mo,

 Ki nsa ma reti abo Re,

 Lati mu mi lo s’ ile;

 Olugbala, Olugbala,

Yara k’o ma bo Kankan. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 57 - Wo oju sanma ohun ni. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post