Yoruba Hymn APA 45- Wa, enyin olope, wa
APA 45
1. Wa, enyin olope, wa,
Gbe orin ikore ga:
Ire gbogbo ti wole
K’ otutu oye to de:
Olorun Eleda wa
L’o ti pese f’ aini wa;
Wa k’a re ’le Olorun
Gbe orin ikore ga.
2. Oko Olorun l’ aiye,
Lati s’ eso iyin Re;
Alikama at’ epo
Ndagba f’ aro tab’ ayo:
Ehu na, ipe tele,
Siri oka nikehin;
Oluwa ’kore, mu wa
Je eso rere fun O.
3. N’tori Olorun w ambo,
Y’o si kore Re sile;
On o gbon gbogbo panti
Kuro l’ oko Re n’jo na :
Y’o f’ ase f’ awon Angel’
Lati gba epo s’ ina,
Lati ko alikama
Si aba Re titi lai.
4. Beni, ma wa, Oluwa
Si ikore ikehin;
Ko awon enia Re jo
Kuro l’ ese at’ aro:
So won di mimo lailai
Kin won le ma ba O gbe:
Wa t’ Iwo t’ Angeli Re
Gbe orin ikore ga. Amin.
This is Yoruba Anglican hymns, APA 45 - Wa, enyin olope, wa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.