Yoruba Hymn APA 31 - Bi mo ti yo, lati gb’ oro

Yoruba Hymn APA 31 - Bi mo ti yo, lati gb’ oro

 Yoruba Hymn  APA 31- Bi mo ti yo, lati gb’ oro

APA 31

 1. Bi mo ti yo, lati gb’ oro

 L’ enu awon ore;

 Pe, “Ni Sion ni k’ a pe si

 K’ a p’ ojo mimo mo.


2. Mo f’ onata at’ ekun re

 Ile t’ a se loso,

 Ile t’ a ko fun Olorun;

 Lati fi anu han.


3. S’ agbala ile ayo na,

 L’ eya mimo si lo,

 Omo Dafidi wa lor’ ite,

 O nda ejo nibe.


4. O gbo iyin at’ igbe wa;

 Bi ohun eru re

 Ti nya elese sib’ egbe,

 A nyo ni wariri.


5. K’ ibukun pelu ibe na

 Ayo nigbakugba;

 K’ a fi ore ati ore,

 F’ awon tin sin nibe.

 

6. Okann mi bebe fun Sion

 Nigbati emi wa;

 Nibe ni batan at’ ore

 At’ Olugbala wa. Amin.

 Yoruba Hymn  APA 31- Bi mo ti yo, lati gb’ oro

This is Yoruba Anglican hymns, APA 31 - Bi mo ti yo, lati gb’ oro. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post