Yoruba Hymn APA 26 - Olusagutan eni re

Yoruba Hymn APA 26 - Olusagutan eni re

 Yoruba Hymn  APA 26 - Olusagutan eni re

APA 26

 1. Olusagutan eni re

 Fi oju Re han wa,

 ’Wo fun wa n’ ile adura

 M’ okan wa gbadura.


2. K’ ife ati Alafia

 K’ o ma gbe ile yi;

 F’irora f’ okan iponju

 M’ okan ailera le.

 

3. K’ a fi ’gbagbo gbo oro Re,

 K’ a fi ’gbagbo bebe;

 Ati niwaju Oluwa

 K’ a se aroye wa. Amin.

Yoruba Hymn  APA 26 - Olusagutan eni re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 26 - Olusagutan eni re. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post