Yoruba Hymn APA 23 - Oluwa, ojo t’ o fun wa pin
APA 23
1. Oluwa, ojo t’ o fun wa pin
Okunkun si de l’ ase Re;
’Wo l’ a korin owuro wa si,
Iyin Re y’ o m’ ale wa dun.
2. A dupe ti Ijo Re ko nsun,
B’ aiye ti nyi lo s’ imole,
O si nsona ni gbogbo aiye,
Ko si simi tosan-toru.
3. B’ ile si tin mo lojojumo
Ni orile at’ ekusu,
Ohun adura ko dake ri,
Be l’orin iyin ko dekun.
4. Orun t’ o wo fun wa, si ti la
S’ awon eda iwo-orun,
Nigbakugba lie nu sin so
Ise ’yanu Re di mimo.
5. Be, Oluwa, lai n’ ijoba Re,
Ko dabi ijoba aiye:
O duro, o sin se akoso
Tit’ eda Re o juba Re. Amin
Yoruba Hymn APA 23 - Oluwa, ojo t’ o fun wa pin
This is Yoruba Anglican hymns, APA 23 - Oluwa, ojo t’ o fun wa pin. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.