Yoruba Hymn APA 14 - Ife Re da wa si loni
APA 14
1. Ife Re da wa si loni,
L’ are, a si dubule;
Ma so wa ni ’dake oru,
K’ ota ma yow a lenu:
Jesu, se olutoju wa,
Iwo l’o dun gbekele.
2. Ero at’ alejo l’aiye,
A ngb’ arin awon ota!
Yow a, at’ ile wa l’ ewu,
L’ apa Re ni k’ a sun si;
N’ ijo iyonu aiye pin,
Ka le simi lodo Re. Amin.
This is Yoruba Anglican hymns, Yoruba Hymn APA 14 - Ife Re da wa si loni. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.