Yoruba Hymn APA 13 - Orun fere wo na
APA 13
1. Orun fere wo na,
Ojo lo tan;
K’ ife k’ o ji dide
K’o rubo asale.
2. Bi Jesu lor’ igi
Ti teriba,
T’o jowo emi Re
Le Baba Re lowo;
3. Be ni mo f’ emi mi
Fun l’ afuntan,
Nipamo Re mimo
L’ emi gbogbo saw a.
4. Nje emi o simi
Lodo Re je;
Laije k’ ero kanso
Yo okan mi l’ enu.
5. ’Fe Tire ni sise
L’ onakona:
Mo d’ oku s’ ara ni,
Ati s’ ohun gbogbo.
6. Bel’ emi ye: sugbon
Emi ko, On
Ni mbe laye n’nu mi,
L’ agbara ife Re.
7. Metalokan Mimo
Olorun kan,
L’ai ki ’m sa je Tire. Amin.
This is Yoruba Anglican hymns, Yoruba Hymn APA 13 - Orun fere wo na. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.