Yoruba Hymn APA 12 - A gboju soke si O

Yoruba Hymn APA 12 - A gboju soke si O

Yoruba Hymn APA 12 - A gboju soke si O

APA 12

1. A gboju soke si O,

At’ owo ati okan;

Tewogba adura wa,

B’ o tile se ailera.


2. Oluwa je k’a mo O,

Je k’a mo oruko Re;

Je k’ awa se ife Re,

Bi nwon tin se li orun.


3. Nigbati a sun l’ oru,

So wa, k’o duro ti wa;

Nigbati ile si mo,

K’a ji, k’a f’iyin fun O. Amin. 

This is Yoruba Anglican hymns, APA 12 - Mo ji, mo ji, ogun orun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post